Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àtẹ ìsọfúnni tó wà ní ojú ìwé 19 sí 22 fi ìròyìn ìgbòkègbodò àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ọdún iṣẹ́ ìsìn 2001 hàn.