Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ohun tí Monothelitism fi kọ́ni ni pé bí Kristi tilẹ̀ jẹ́ Ọlọ́run àti ènìyàn, síbẹ̀ ọ̀kan ṣoṣo ni ìfẹ́ inú rẹ̀.