Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ṣáájú ìgbà náà, ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé orí pẹpẹ ni Kéènì àti Ébẹ́lì pẹ̀lú ti rú ẹbọ wọn sí Jèhófà.—Jẹ́nẹ́sísì 4:3, 4.