Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwọn tó ń tu ọkọ̀ òkun láti erékùṣù Mẹditaréníà sí àwọn ilẹ̀ bèbè etíkun làwọn èèyàn máa ń pè ní “Àwọn Èèyàn Òkun.” Ó ṣeé ṣe káwọn Filísínì wà lára wọn.—Ámósì 9:7.