Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé e Jèhófà ni orúkọ Ọlọ́run tó ni Bíbélì. A lè rí orúkọ yìí nínú Sáàmù 83:18 nínú ọ̀pọ̀ Bíbélì.