Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Dáfídì kọ àwọn sáàmù bíi mélòó kan tó fi yin Jèhófà lógo nítorí pé ó yọ ọ́ nínú ewu.—Bí àpẹẹrẹ, wo àkọlé Sáàmù 18, 34, 56, 57, 59, àti 63.