Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Gẹ́gẹ́ bí ohun táwọn kan fojú bù, ó lé ní ìdá méje àwọn Júù tó kú láwọn àgbègbè tí ilẹ̀ Róòmù ń ṣàkóso rẹ̀.