Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù làwọn èèyàn mọ Sọ́ọ̀lù sí jù lóde òní. Àmọ́ Sọ́ọ̀lù tó jẹ́ orúkọ rẹ̀ lédè àwọn Júù ló wà nínú ọ̀pọ̀ jù lọ ẹsẹ Bíbélì tá a tọ́ka sí nínú àpilẹ̀kọ yìí.—Ìṣe 13:9.