Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ile-Iṣọ Naa ti September 15, 1983, ojú ìwé 30 àti 31 ṣe àlàyé tó kan ọkọ àtaya, èyí tó yẹ ká gbé yẹ̀ wò.