Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nítorí pé àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà kò dá sí ọ̀ràn ìṣèlú, ìjọba fòfin de iṣẹ́ wọn ní July 4, ọdún 1940.