Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ohun tí Jákọ́bù ń jíròrò fi hàn pé àwọn alàgbà tí wọ́n tún jẹ́ “olùkọ́” nínú ìjọ ló dìídì ń bá wí. (Ják. 3:1) Àwọn ọkùnrin wọ̀nyí ló yẹ kí wọ́n jẹ́ àpẹẹrẹ nínú fífi ọgbọ́n Ọlọ́run hàn, síbẹ̀ gbogbo wa lè kẹ́kọ̀ọ́ látinú ìmọ̀ràn Jákọ́bù.