Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Tó o bá fẹ́ mọ̀ bóyá ibi kan ní ti gidi ni Amágẹ́dọ́nì, wo àpilẹ̀kọ náà “Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé,” lójú ìwé 31.