Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d Èrò àwọn kan ni pé Bíbélì ta ko ara rẹ̀ lórí ohun tó sọ nípa bí ọ̀dá yẹn ṣe gùn tó. Wo àpótí tó wà lójú ìwé 19.