Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Arákùnrin Bolfenk Moc̆nik kú ní ọjọ́ kọkànlá oṣù April, ọdún 2008, nígbà tá à ń ṣàkójọ àpilẹ̀kọ yìí.