Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Ibì kan ṣoṣo tí Bíbélì èdè Gíríìkì ìjímìjí tún ti lo gbólóhùn náà “fúnra rẹ̀” ni Ìṣe 12:10, níbi tó ti sọ pé ẹnubodè onírin kan ṣí “fúnra rẹ̀.”