Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Tó o bá kọ́kọ́ ka Sáàmù 83 kó o tó máa ka àpilẹ̀kọ yìí lọ, èyí á ṣe ọ́ láǹfààní, nítorí pé yóò jẹ́ kó o mọ ohun tó wà nínú àwọn ẹsẹ yẹn dáadáa.