Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a O lè rí àwòrán àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn láwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba kan. Àmọ́, ńṣe la fi irú àwòrán bẹ́ẹ̀ ṣe ọ̀ṣọ́ sára àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba wọ̀nyẹn, wọn kì í ṣe ère fún ìjọsìn. Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kì í gbàdúrà sáwọn àwòrán wọ̀nyí, a kì í sì í forí balẹ̀ fún wọn.