Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Lórílẹ̀-èdè Ireland, àwọn àdúgbò tí wọ́n ti pààlà wọn láti ọ̀rúndún kọkànlá ni wọ́n ń pè ní ìlú. Àwọn ìlú wọ̀nyí tóbi jura wọn lọ, ọgọ́rọ̀ọ̀rún ilé gbígbé lè wà nínú àwọn kan lára àwọn ìlú náà. Orúkọ àwọn ìlú yìí ni wọ́n sì máa fi ń kówèé ránṣẹ́ lórílẹ̀-èdè Ireland.