Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nígbà kan, àpọ́sítélì Pétérù náà sọ ohun kan tó jọ èyí níbi batisí kan, ó ní: “Ẹnikẹ́ni ha lè ka omi léèwọ̀?”—Ìṣe 10:47.