Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Èdè Árámáíkì ni wọ́n fi kọ díẹ̀ lára Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù. Ó ṣe kedere pé èdè Hébérù ni Mátíù kọ́kọ́ fi kọ ìwé Ìhìn Rere tó ń jẹ́ orúkọ ẹ̀, ó sì lè jẹ́ pé òun fúnra ẹ̀ náà ló túmọ̀ ẹ̀ sédè Gíríìkì.
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 13]
Àjákù ìwé àfọwọ́kọ Septuagint tí wọ́n kọ lédè Gíríìkì
[Credit Line]
Látọwọ́ Israel Antiquities Authority