Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ọ̀pọ̀ èèyàn ló ti mọ orúkọ Ọlọ́run sí “Jèhófà” lédè Yorùbá, bó sì ṣe wà nínú ọ̀pọ̀ Bíbélì nìyẹn.