Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Sólómọ́nì yìí sì tún wá ní orúkọ kejì tó ń jẹ́ Jedidáyà, tó túmọ̀ sí “Àyànfẹ́ Jáà.”—2 Sám. 12:24, 25.