Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn atúmọ̀ Bíbélì kan máa ń túmọ̀ ẹsẹ yìí lọ́nà tó fi jọ pé ikú aboyún nìkan ló lè mú kí wọ́n pa ẹni tó fa jàǹbá náà. Àmọ́ nínú èdè Hébérù ìpilẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n fi kọ Bíbélì, ikú aboyún tàbí ọmọ inú rẹ̀ ni òfin yẹn ń sọ.