Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tí wọ́n bá sọ pé ọkùnrin fún obìnrin “lóògùn” jẹ, ohun tíyẹn túmọ̀ sí ni pé ọkùnrin yẹn fi oògùn tó máa jẹ́ kí obìnrin kan nífẹ̀ẹ́ òun tipátipá sínú oúnjẹ tàbí ọtí tó gbé fún un. Èyí yàtọ̀ sí lílo oògùn olóró fún obìnrin kan kí wọ́n sì wá fi tipátipá bá a lòpọ̀. Tírú ẹ̀ bá ṣẹlẹ̀, àwọn èèyàn gbà pé obìnrin yẹn ò mọwọ́ mẹsẹ̀.