Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Lọ́dún 1840, òkè kan bẹ̀rẹ̀ sí í tú àwọn nǹkan gbígbóná jáde, ìgbà táwọn nǹkan gbígbóná yẹn sì tutù tán, ó di òkè ńlá tí wọ́n ń pè ní Òkè Árárátì lóde òní. Ó ga ju pẹ̀tẹ́ẹ̀sì alájà ẹgbẹ̀rún kan àti ọgọ́rùn-ún mẹ́fà [1,600] lọ, yìnyín sì máa ń bo òkè yìí jálẹ̀ ọdún.