Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Nínú Ìwé Mímọ́ ní Ìtúmọ̀ Ayé Tuntun, àwọn ọ̀rọ̀ Gíríìkì kan wà tá a tún túmọ̀ sí “ìfẹ́ni oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́.” Torí náà, kì í ṣe inú Róòmù 12:10 nìkan ni “ìfẹ́ni oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́” ti fara hàn nínú Bíbélì yìí, ó tún wà nínú Fílípì 1:8 àti 1 Tẹsalóníkà 2:8.