d Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i, ka orí 3 tá a pe àkòrí rẹ̀ ní “Kí Ni Ọlọ́run Ní Lọ́kàn Tó Fi Dá Ilẹ̀ Ayé?” àti orí 5 tá a pe àkòrí rẹ̀ ní “Ìràpadà—Ẹ̀bùn Tó Ṣeyebíye Jù Lọ Tí Ọlọ́run Fúnni” nínú ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é.