Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Kíkà tí ọ̀gbẹ́ni Tischendorf lè ka Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù tí wọ́n tú sí èdè Gíríìkì jẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ ọ́n dáadáa ní ilé àwọn ọkùnrin ajẹ́jẹ̀ẹ́ ìnìkàngbé tó wà ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Òkè Sínáì, ìyẹn St. Catherine’s Monastery, ìwé yìí sì wà lára ìwé tó tíì pẹ́ jù lọ tí wọ́n tíì ṣàwárí rẹ̀. Wọ́n máa ń pe ìwé àfọwọ́kọ yẹn ní Codex Sinaiticus.