Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Nínú ìwé Diutarónómì, Mósè tẹnu mọ́ ọn pé ìbẹ̀rù Ọlọ́run ló gbọ́dọ̀ máa darí ìgbésí ayé àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run.—Diutarónómì 4:10; 6:13, 24; 8:6; 13:4; 31:12, 13.