Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ó dùn mọ́ni láti mọ̀ pé dípò tí àwọn kan lára àwọn ìwé atúmọ̀ èdè àti àwọn ìwé tó túmọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ inú Bíbélì á fi máa sọ ohun tí ọ̀rọ̀ kan wulẹ̀ túmọ̀ sí, ńṣe ni wọ́n máa ń sọ ìtumọ̀ tí Bíbélì kan pàtó, irú bíi King James Version, bá lò fún ọ̀rọ̀ náà.