Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Díẹ̀ lára àwọn ìlérí tí Jóṣúà rí ìmúṣẹ rẹ̀ rèé: Jèhófà máa fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ilẹ̀ wọn. (Fi Jẹ́nẹ́sísì 12:7 wé Jóṣúà 11:23.) Jèhófà máa dá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nídè kúrò ní Íjíbítì. (Fi Ẹ́kísódù 3:8 wé Ẹ́kísódù 12:29-32.) Jèhófà máa bójú tó àwọn èèyàn rẹ̀.—Fi Ẹ́kísódù 16:4, 13-15 wé Diutarónómì 8:3, 4.