Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ó ṣì di òpin ẹgbẹ̀rún ọdún Ìjọba Jésù kí “àwọn àgùntàn mìíràn” tó di ọmọ Ọlọ́run. Àmọ́, níwọ̀n bí wọ́n ti ya ara wọn sí mímọ́ fún Ọlọ́run, wọ́n lẹ́tọ̀ọ́ láti máa pe Ọlọ́run ní “Baba,” a sì lè kà wọ́n sí ara agboolé àwọn olùjọsìn Jèhófà.—Jòh. 10:16; Aísá. 64:8; Mát. 6:9; Ìṣí. 20:5.