Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Báálì ni òrìṣà tó gba iwájú jù lọ tí àwọn ọmọ Kénáánì ń sìn, Áṣítórétì sì ni wọ́n gbà pé ó jẹ́ ìyàwó rẹ̀.