Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ó jẹ́ àṣà àwọn èèyàn ìgbà yẹn láti ní orúkọ kejì tó jẹ́ èdè Hébérù tàbí orúkọ ilẹ̀ òkèèrè míì. Orúkọ Júù tí Máàkù ń jẹ́ ni Yohanan, tá a mọ̀ sí Jòhánù lédè Yorùbá. Orúkọ àpèlé rẹ̀ lédè Látìn ni Marcus, tàbí Máàkù.—Ìṣe 12:25.