Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Èròǹgbà tí Jerome gbé kalẹ̀ ní nǹkan bí ọdún 383 Sànmánì Kristẹni yìí, wọ́pọ̀ láàárín àwọn tí wọ́n gbà gbọ́ pé Màríà jẹ́ wúńdíá títí ọjọ́ ayé rẹ̀. Nígbà tó yá, Jerome sọ pé èròǹgbà òun yìí lè má tọ̀nà, àmọ́ lọ́kàn ọ̀pọ̀ èèyàn àti lọ́kàn àwọn aláṣẹ Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì, èrò náà ṣì tọ̀nà.