Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Iṣẹ́ ọpọlọ yìí ni nǹkan tẹ́nì kan ṣe tí kò fúnni láṣẹ láti ṣe ẹ̀dà rẹ̀, irú bí orin, ìwé tàbí ètò orí kọ̀ǹpútà, bóyá èèyàn ṣe é sorí bébà ni tàbí ó gbé sorí ẹ̀rọ abánáṣiṣẹ́. Lílo orúkọ ilé iṣẹ́, ẹ̀tọ́ oní-nǹkan, àṣírí ilé iṣẹ́ àti ìkéde láìgba àṣẹ tún wà lára nǹkan tá à ń sọ yìí.