Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ilé Ìṣọ́ May 15, 2008, ojú ìwé 29, ṣàlàyé iṣẹ́ tí ọ̀kọ̀ọ̀kan ìgbìmọ̀ mẹ́fẹ̀ẹ̀fà ti Ìgbìmọ̀ Olùdarí ń ṣe.