Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àkọsílẹ̀ náà sọ pé Jèhófà ti ‘sé ilé ọlẹ̀ Hánà,’ kò sí ẹ̀rí pé inú Ọlọ́run kò dùn sí obìnrin onírẹ̀lẹ̀ àti olóòótọ́ yìí. (1 Sámúẹ́lì 1:5) Nígbà míì, Bíbélì máa ń sọ pé Ọlọ́run ló ṣe àwọn nǹkan kan nítorí pé ó gbà wọ́n láyè pé kí wọ́n ṣẹlẹ̀ fún àwọn àkókò kan.