Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Bí o kò bá tíì ka Bíbélì rí, gbìyànjú kó o kọ́kọ́ ka àkọ́sílẹ̀ alárinrin nípa iṣẹ́ òjíṣẹ́ Jésù nínú ìwé Máàkù.