Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d Ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ti ran ọ̀pọ̀ lọ́wọ́ láti lóye àwọn ẹ̀kọ́ inú Bíbélì. Bí àpẹẹrẹ, orí 17, ṣàlàyé ohun tí Ìwé Mímọ́ sọ nípa àdúrà.