Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Àwọn tó kọ ìròyìn tó wà nínú ìwé ọdọọdún náà, SIPRI Yearbook 2009 ni ọ̀gbẹ́ni Shannon N. Kile, tó jẹ́ olùṣèwádìí àgbà àti olórí àwọn tó ń rí sí ọ̀ràn ohun ìjà runlérùnnà ti àjọ SIPRI Arms Control and Non-proliferation Programme, ọ̀gbẹ́ni Vitaly Fedchenko, tó jẹ́ olùṣèwádìí nípa ohun ìjà runlérùnnà ti àjọ SIPRI Arms Control and Non-proliferation Programme àti ọ̀gbẹ́ni Hans M. Kristensen, olùdarí ìsọfúnni nípa ohun ìjà runlérùnnà fún àwọn Onímọ̀ Sáyẹ́ǹsì Ilẹ̀ Amẹ́ríkà.