Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Fún àlàyé tó kún rẹ́rẹ́ lórí ìtúmọ̀ tẹ̀mí tí àpèjúwe Pọ́ọ̀lù yìí ní, ka Ilé Ìṣọ́, November 15, 1990, ojú ìwé 27.