Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nígbà tí à ń múra láti tẹ àpilẹ̀kọ yìí jáde ni Arákùnrin Harley Harris kú gẹ́gẹ́ bí olóòótọ́ sí Jèhófà.