Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé lórí bá a ṣe lè gbàdúrà tí Ọlọ́run á gbọ́, ka orí 17 nínú ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é.