Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwọn ọ̀rọ̀ tí Dáfídì sọ nínú Sáàmù Kẹjọ tún jẹ́ àsọtẹ́lẹ̀ tó ń tọ́ka sí ọkùnrin pípé náà Jésù Kristi.—Héb. 2:6-9.