Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Èrò yìí kò bá Ìwé Mímọ́ mu. Bíbélì sọ pé, gbogbo nǹkan tí Ọlọ́run dá ló jẹ́ pípé, ibòmíì ni ìdíbàjẹ́ ti wá. (Diutarónómì 32:4, 5) Nígbà tí Jèhófà dá gbogbo nǹkan tán sórí ilẹ̀ ayé, ó sọ pé, gbogbo wọn ló “dára gan-an.”—Jẹ́nẹ́sísì 1:31.