Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ẹ̀rí fi hàn pé Àkúnya Omi tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ló pa ọgbà Édẹ́nì rẹ́ pátápátá. Ìwé Ìsíkíẹ́lì 31:18 sọ pé, “àwọn igi Édẹ́nì” ti pa rẹ́ tipẹ́tipẹ́ ní ọgọ́rùn-ún ọdún keje ṣáájú Sànmánì Kristẹni. Nítorí náà, gbogbo àwọn tó ń wá ọgbà Édẹ́nì lẹ́yìn ìgbà náà kò lè rí i mọ́.