Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Ó gbàfiyèsí pé àwọn onímọ̀ ìṣègùn òde òní ti ṣàwárí pé egungun ìhà ní agbára tó kàmàmà láti wo ara rẹ̀ sàn. Egungun ìhà yàtọ̀ sí àwọn egungun inú ara yòókù, nítorí pé tuntun míì máa ń yọ jáde tí awọ ẹran tó yí i ká kò bá tíì bà jẹ́.