Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Àwọn nọ́ńbà wọ̀nyí ń tọ́ka sí orí àti ìpínrọ̀ nínú ìwé Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí (gt). Tó o bá fẹ́ mọ̀ lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́ nípa àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó sọ nípa iṣẹ́ òjíṣẹ́ tí Jésù ṣe kẹ́yìn, wo àtẹ tó wà ní ojú ìwé 290 nínú ìwé “All Scripture Is Inspired of God and Beneficial,” lédè Gẹ̀ẹ́sì. Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é.