Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ náà, “yín” tó wà nínú gbólóhùn náà, “ní àárín yín” jẹ́ ọ̀rọ̀ ẹlẹ́ni púpọ̀ nínú èdè Gíríìkì ìpilẹ̀ṣẹ̀, ohun táwọn Bíbélì kan lò nìyẹn, ó sì tọ́ka sí àwọn Farisí tí Jésù ń bá sọ̀rọ̀. Ó dájú pé, kì í ṣe àyípadà tí àwọn Farisí yẹn ṣe tàbí bí ọkàn wọn ṣe rí ni Jésù ń sọ.